Ruth Negga
Ruth Negga ( /ˈneɪɡə/ NAY-gə;[1] tí a bí ní ọ́jọ́ keje oṣù kíní ọdún 1982)[2] jẹ́ osere Ethiopian-Irish ti a mo fun ipa re ni jara telifisonu AMC Preacher ati ninu fiimu Loving. .
Negga ti kopa ninu awon fiimu bi Capital Letters (2004) (ti a mo si Trafficked ni awon orilede mi), Isolation (2005), Breakfast on Pluto (2005) ati Warcraft (2016).[3] Awon ise imi toti ko pa ninu re je BBC mini-series Criminal Justice, RTÉ Love/Hate, E4 Misfits, and ABC's Marvel's Agents of S.H.I.E.L.D. Negga bere ipa re gegebi Tulip O'Hare ninu Preacher ni odun 2016.
Fun ipa re gegebi Mildred Loving ni Loving, Won fi oruko Negga sile fun osere ti odaro julo ni Academy Award, Golden Globe Award , Independent Spirit Award , Critics' Choice Movie Award osi gba ami eye Irish Film and Television Award fun osere ti o dara julo win tun fi oruko sile fun BAFTA Award gegebi osere tuntun ti odara julo. Ni odun 2020, won fun ni ipo kewa lori The Irish Times ninu awon osere Ireland ti o dara julo.[4]
Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni odun 1982 ni abi Negga si ilu Addis Ababa, Ethiopia,[5] iya re Nora je omo Ireland, Baba re, Dr Negga je omo Ethiopia. Awon obi re pade nigba ti mama re n sise gegebi nursi ni ilu Ethiopia.[6] Negga ti o je omo kan ti awon obi re bi gbe ni Ethiopia titi to fi pe omo odun merin. Baba re ku nipase ijamba oko, nigba ti owa ni omo odun meje.[7] Ilu Limerick, Ireland, ni odagba si, osi tin gbe ni ilu London lati odun 2006.[8][9]
Negga keko ni Samuel Beckett Centre ni Trinity College, Dublin,[10] o gba oye BA ni eko imo sise ere.
Ise
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Negga se ijade pelu fiimu Irish kan ti on je Capital Letters (2004), ipa Taiwo lo ko ninu ere na. Lehin igba na o ko pa Mary ninu Isolation ni odun to tele. Ko to di igba yi, ise theatre ni on se.[11] Lehin igba ti Neil Jordan ri Negga se ere, o ni lati tun ere na ko, owa pe akole re ni Breakfast on Pluto ki o ba le wa ninu ere na. Oti kopa ninu Colour Me Kubrick (2005), pelu John Malkovich, ati awon ere kuku The Four Horsemen, 3-Minute 4-Play ati Stars.
Lori telifisionu Negga ti kopa ninu awon ere Doctors, Criminal Justice ati jara Irish Love Is the Drug. O ko pa Doris "Sid" Siddiqi ninu jara BBC Three eyi ti oje Personal Affairs, legbe Laura Aikman, Annabel Scholey ati Maimie McCoy.[12] Negga kopa Rosie ninu awon jara alakoko titi RTÉ's Love/Hate.[13]
Negga kopa gegebi Dame Shirley Bassey ninu ere TV BBC Shirley ni odun 2011 osi gba ami eye IFTA osere ti odara julo fun ipa. Ipa re ninu theartre je Duck ni Titus Andronicus ati Lay Me Down Softly.[14] Ni odun 2007, obere ise pelu Irish theatrical group ni Pan Pan Theatre. Ni odun 2010, o ko pa Ophelia ninu ifilole Hamlet lori itage. Otun fi ohun re kale fun ere Dark Souls II, okopa Shanalotte, ti atu mosi "Emerald Herald".
Odun 2013 ni a gba Negga ki o wa kopa Raina ni jara American Agents of S.H.I.E.L.D..[15][16]. Ose afihan ninu ipele metadilogun titi eto na[17] O ko ipa ninu fiimu Steve McQueeneyi ti ogba emi eye Oscar ti akole re je 12 Years a Slave, sugbon won yo ipa re ninu ere na.[18] Ojo kedogbon osu keta odun 2015, Negga ko ipa Tulip O'Hare ninu jara AMC, Preacher, ti o jade ni odun 2016.[19]
Ni odun 2016, Negga kopa ninu Loving, ti won se ifi lo le eh ni 2016 Cannes Film Festival lehin na ni Toronto International Film Festival.[20][21] Fiimu na da lo ri awon Lovings, toko tiyawo ti won ni awo ara to yato awon odun 1950s ati 1960s ni Virginia, igbe yawo won fju ba ile ejo to ga ju lo, ti esi won deni Loving v. Virginia. Negga di ilu moka fun ipa yi,[22] ati pe ogba yiyan ati emi yi lopolopo fun Ami eye Academy fun osere ti odara julo, Ami eye Golden Globe fun ese ori irin eyi ti o dara julo, ati BAFTA Rising Star Award.[23][24]
Negga kopa ninu ise Gate Theatre’ ti odun 2018 (Yaël Farber lo dari e) ti Hamlet,[25][26] ti otun tunse ni St. Ann’s Warehouse ni orisun 2020.[27][28]
Igbesi aye ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Negga ati Dominic Cooper n fera wan ni ibere odun 2010. Won koko pade ni odun 2009 lori ere ori itage Phèdre pelu Helen Mirren. Awon mejeji jo n gbe ni Primrose Hill titi ilu london.[29][30] Won fe ra wan fun odun mefa; sugbon Negga ogba odun die ki awon oniroyin to gbo pe won o fera mo titi di osu kerin odun 2018.[31][32] Negga ti kopa niwaju Cooper ninu fiimu AMC Preacher,ni bi ti won ti kopa ololufe, won si ni ore timotimo ni awon mejeji[32]
Itage
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Duck (as Cat): Traverse Theatre, Edinburgh (2003)
- Phèdre (as Aricia): National Theatre London (2009)
- Hamlet (as Ophelia): National Theatre London (2010/11)
- Playboy of the Western World (as Pegeen Mike): Old Vic Theatre London (2011)
- Hamlet (as Hamlet): Gate Theatre, Dublin (2018)
Filmography
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fiimu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2012 | The Samaritan | Iris | |
2013 | World War Z | WHO doctor | |
2013 | 12 Years a Slave | Celeste | Deleted scenes[33] |
2013 | Jimi: All Is by My Side | Ida | |
2014 | Noble | Joan | |
2014 | Of Mind and Music | Jessica | |
2015 | Iona | Iona | |
2016 | Loving | Mildred Loving | |
2016 | Warcraft | Queen Taria | |
2019 | Ad Astra | Helen Lantos | |
TBA | Passing | Claire Kendry | Post-production |
Tẹlifisiọnu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2013–2015, 2018 |
Agents of S.H.I.E.L.D. | Raina | Recurring role (seasons 1–2) Guest role (season 5) |
2016–2019 | Preacher | Tulip O'Hare | Main role Also executive producer |
Awon ere fidio
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role |
---|---|---|
2011 | El Shaddai: Ascension of the Metatron | Ishtar |
2014 | Dark Souls II | Shanalotte (Emerald Herald) |
Awọn ami eye ati awọn yiyan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni odun 2003 won yan Negga gegebi osere tuntun ti o dara julo ni Olivier Awards.[8] Won yan fun irawo ti on goke julo ni odun 2006 ni Berlin Film Festival. Oti gba iyin rere fun ipa re gegebi Mildred Loving ninu fiimu odun 2016 eyi a pe ni Loving, oti gba Academy Award, Critic's Choice, ati Golden Globe Award nominations fun osere ti o dara julo
Year | Association | Category | Work | Result |
---|---|---|---|---|
2005 | Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Supporting Role – Film | Breakfast on Pluto | Wọ́n pèé |
Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Lead Role – Film | Isolation | Wọ́n pèé | |
2011 | Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Supporting Role – Television | Love/Hate | Wọ́n pèé |
2012 | Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Supporting Role – Television | Misfits | Wọ́n pèé |
Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Lead Role – Television | Shirley | Gbàá | |
Royal Television Society | RTS Television Award for Best Actor (Female) | Shirley | Wọ́n pèé | |
Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Supporting Role – Television | Secret State | Wọ́n pèé | |
2015 | British Academy Scotland Awards | Best Actress in Film | Iona | Wọ́n pèé |
London Film Critics Circle Awards | British/Irish Actress of the Year | Loving and Iona | Wọ́n pèé | |
2016 | New York Film Critics Online | Best Breakthrough Performer | Loving | Gbàá |
African-American Film Critics Association | Best Actress | Gbàá | ||
Alliance of Women Film Journalists | Best Actress | Gbàá | ||
Black Reel Awards | Outstanding Actress | Gbàá | ||
Palm Springs International Film Festival | Rising Star Award | Gbàá | ||
Santa Barbara International Film Festival | Vituosos Award | Gbàá | ||
Satellite Awards | Best Actress (tied with Isabelle Huppert) | Gbàá | ||
Academy Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
AACTA International Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Austin Film Critics Association | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
British Academy Film Awards | BAFTA Rising Star Award | Wọ́n pèé | ||
Critics' Choice Movie Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Dallas–Fort Worth Film Critics Association Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Detroit Film Critics Society Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Florida Film Critics Circle Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Golden Globe Awards | Best Actress in a Motion Picture – Drama | Wọ́n pèé | ||
Gotham Independent Film Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Independent Spirit Awards | Best Female Lead | Wọ́n pèé | ||
London Film Critics Circle Awards | British/Irish Actress of the Year | Wọ́n pèé | ||
NAACP Image Awards | Outstanding Actress in a Motion Picture | Wọ́n pèé | ||
Online Film Critics Society Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
San Diego Film Critics Society Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
San Francisco Film Critics Circle Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
St. Louis Gateway Film Critics Association Awards | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Washington D.C. Area Film Critics Association | Best Actress | Wọ́n pèé | ||
Irish Film & Television Academy | Best Actress in a Supporting Role – Drama | Agents of S.H.I.E.L.D. | Wọ́n pèé | |
2019 | Daytime Emmy Awards | Outstanding Performer in an Animated Program | Angela's Christmas | Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ruth Negga's Best Worst Jokes". Vogue. December 7, 2016. Retrieved August 26, 2020.
- ↑ http://www.goldenglobes.com/person/ruth-negga
- ↑ "Oscars 2017: Ruth Negga nominated for best actress award". The Irish Times. https://www.irishtimes.com/culture/film/oscars-2017-ruth-negga-nominated-for-best-actress-award-1.2949162.
- ↑ https://www.irishtimes.com/culture/film/the-50-greatest-irish-film-actors-of-all-time-in-order-1.4271988
- ↑ "Africa from A to Z: Fast facts on the 55 states - Ethiopia". Archived from the original on 12 December 2017. https://web.archive.org/web/20171212084450/https://southafrica-info.com/africa-from-a-to-z-fast-facts-55-states/#ethiopia. Retrieved 12 December 2017.
- ↑ http://www.limerickleader.ie/news/home/207986/-Always-a-star-in-the.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20090529132154/http://www.cafebabel.com/eng/article/18984/ruth-negga-a-star-without-a-label.html
- ↑ 8.0 8.1 "Rising Star: Ruth Negga, actor". https://www.theguardian.com/theobserver/2006/jan/08/features.magazine27.
- ↑ Alan Owens, "Ruth's star is on the rise with BBC" Archived 2014-01-06 at the Wayback Machine., Limerick Leader, 20 August 2011
- ↑ Cineuropa – Interviews – Ruth Negga, Actress. Cineuropa.org.
- ↑ Cineuropa – Interviews – Ruth Negga, Actress. Cineuropa.org
- ↑ "P.A.s cast have Secs Appeal on BBC Three". BBC Press Office. 2 June 2008.
- ↑ Notaro, Vicki (23 May 2016). "How Oscar-tipped Ruth Negga's star has finally ascended...". Irish Independent. http://www.independent.ie/entertainment/how-oscartipped-ruth-neggas-star-has-finally-ascended-34730596.html. Retrieved 23 May 2016.
- ↑ Company Members: Ruth Negga Archived 29 May 2009 at the Wayback Machine., National Theatre. April 2009.
- ↑ "Jere Burns Upped On 'Justified', Michael Rispoli, Ruth Negga, Danielle Nicolet In Arcs". Deadline.com.
- ↑ Declassifying Marvel's Agents of S.H.I.E.L.D. Ep. 105: Girl in the Flower Dress Archived 13 October 2013 at the Wayback Machine.. Marvel.com.
- ↑ Notaro, Vicki (23 May 2016). "How Oscar-tipped Ruth Negga's star has finally ascended...". Irish Independent. http://www.independent.ie/entertainment/how-oscartipped-ruth-neggas-star-has-finally-ascended-34730596.html. Retrieved 23 May 2016.
- ↑ Clarke, Donald (17 May 2016). "Negga's 'Loving' performance already generating Oscar buzz". The Irish Times. Retrieved 6 February 2017.
- ↑ "First Casting Announcement for AMC's "Preacher"! - Bloody Disgusting". Bloody-disgusting.com. Retrieved 30 December 2017.
- ↑ Clarke, Donald (17 May 2016). "Negga's 'Loving' performance already generating Oscar buzz". The Irish Times. Retrieved 6 February 2017.
- ↑ "Ruth Negga portrays civil rights activist Mildred Loving". Toronto Star, 10 November 2016, pg. E1.
- ↑ Notaro, Vicki (23 May 2016). "How Oscar-tipped Ruth Negga's star has finally ascended...". Irish Independent. http://www.independent.ie/entertainment/how-oscartipped-ruth-neggas-star-has-finally-ascended-34730596.html. Retrieved 23 May 2016.
- ↑ "Oscar nominations 2017: the full list". Guardian. 24 January 2017. Retrieved 25 January 2017.
- ↑ Brady, Sarah (6 February 2017). "Ruth Negga continues her successful award season run with yet another honour". Irish Independent. Retrieved 25 March 2018.
- ↑ Michael Billington (7 October 2018). "Hamlet/Richard III review – Ruth Negga plays the Prince with priceless precision". The Guardian. Retrieved 4 August 2020.
- ↑ Jennifer O’Brien (29 September 2018). "Theatre review: Hamlet at the Gate Theatre, Dublin". The Times. Retrieved 4 August 2020.
- ↑ Ben Brantley (10 February 2020). "Review: In 'Hamlet,' Ruth Negga Rules as a Player Prince". The New York Times. Retrieved 4 August 2020.
- ↑ Allison Adato (10 February 2020). "Ruth Negga crowns herself a brooding prince in Hamlet: Review". Entertainment Weekly. Retrieved 4 August 2020.
- ↑ Notaro, Vicki (23 May 2016). "How Oscar-tipped Ruth Negga's star has finally ascended...". Irish Independent. http://www.independent.ie/entertainment/how-oscartipped-ruth-neggas-star-has-finally-ascended-34730596.html. Retrieved 23 May 2016.
- ↑ McBride, Caitlin (8 June 2016). "Irish actress Ruth Negga and Dominic Cooper make rare public appearance at Warcraft premiere". Irish Independent. http://www.independent.ie/style/celebrity/celebrity-news/irish-actress-ruth-negga-and-dominic-cooper-make-rare-public-appearance-at-warcraft-premiere-34783050.html. Retrieved 9 June 2016.
- ↑ Marcus, Emily (5 April 2018). "Dominic Cooper and Ruth Negga Split After 8 Years Together". Retrieved 5 April 2018.
- ↑ 32.0 32.1 "Ruth Negga Talks Diversity, Hamlet And Her Split From Dominic Cooper" (in en-US). Marie Claire. 2018-08-08. https://www.marieclaire.co.uk/entertainment/people/ruth-negga-diversity-dominic-cooper-610595.
- ↑ https://www.irishtimes.com/culture/film/negga-s-loving-performance-already-generating-oscar-buzz-1.2650022