Jump to content

Novak Djokovic

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Novak Djokovic
OrúkọNovak Đoković
Orílẹ̀-èdèSérbíà Sérbíà
IbùgbéMónakò Monte Carlo
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kàrún 1987 (1987-05-22) (ọmọ ọdún 37)
Belgrade, Sérbíà
Ìga1.88 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2003
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niDejan Petrovic (2004–2005)
Riccardo Piatti (2005–2006)
Marián Vajda (2006–)
Mark Woodforde (2007)
Todd Martin (2009–2010)
Boris Becker (2013–)
Ẹ̀bùn owó$82,346,218
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tìnovakdjokovic.com
Ẹnìkan
Iye ìdíje652–143 (82.01% in Grand Slam and ATP World Tour main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ54 (10th in the Open Era)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (4 July 2011)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 1 (13 July 2015)[1]
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2008, 2011, 2012, 2013, 2015)
Open FránsìW (2016)
WimbledonW (2011, 2014, 2015)
Open Amẹ́ríkàW (2011)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPW (2008, 2012, 2013, 2014)
Ìdíje Òlímpíkì Bronze medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje37–52
Iye ife-ẹ̀yẹ1
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 114 (30 November 2009)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 287 (13 July 2015)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà1R (2006, 2007)
Open Fránsì1R (2006)
Wimbledon2R (2006)
Open Amẹ́ríkà1R (2006)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Davis CupW (2010)
Hopman CupF (2008, 2013)
Last updated on: 13 July 2015
Signature of Novak Djokovic.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún  Sérbíà
Men's Tennis
Bàbà 2008 Beijing Singles

Novak Djokovic (Kirilliki Serbia: Новак Ђоковић; Novak Đoković; Àdàkọ:IPA-sh; ibi ní Belgrade ọjọ́ ìbí (1987-05-22)Oṣù Kàrún 22, 1987) jẹ́ agbá tẹ́nìs alagbase ará Sérbíà, tó di Ipò kínín ATP mú lati Ọjọ́ kẹrin Oṣù keje Ọ́dún 2011 dé Oṣù keje Ọdún 2012. Djokovic ti gba ife ẹ̀yẹ àwọn enìkan Grand Slam mejo, ó gba àwọń ife-eye idíje ATP World Tour Masters 1000 méjìlá, ó sì tún jẹ́ ọmó-ẹgbẹ́ Ife Eye Davis Sérbíà tó borí ní odún 2010. Ọ̀pọ̀̀ àwọn olùtúwò eré-ìdárayá, olùgbéwò tẹnìs, à̀ti àwọn atayò lọ́́wọ́ àti tẹ́lẹ̀ gbà pé Djokovic ni atayò tẹnìs to gbòkìkíjùlo.[2][3][4][5][6]