Jeļena Ostapenko
Ìrísí
Ostapenko at the 2019 French Open | |||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Àdàkọ:LAT | ||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ibùgbé | Riga, Latvia | ||||||||||
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹfà 1997 Riga, Latvia | ||||||||||
Ìga | 1.77 m | ||||||||||
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 23 April 2012[1] | ||||||||||
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) | ||||||||||
Olùkọ́ni | Marion Bartoli[2] | ||||||||||
Ẹ̀bùn owó | US$ 8,877,147 | ||||||||||
Ẹnìkan | |||||||||||
Iye ìdíje | 237–145 (62.04%) | ||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 3 | ||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 5 (19 March 2018) | ||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 41 (16 March 2020) | ||||||||||
Grand Slam Singles results | |||||||||||
Open Austrálíà | 3R (2017, 2018) | ||||||||||
Open Fránsì | W (2017) | ||||||||||
Wimbledon | SF (2018) | ||||||||||
Open Amẹ́ríkà | 3R (2017, 2018, 2019) | ||||||||||
Àwọn ìdíje míràn | |||||||||||
Ìdíje WTA | RR (2017) | ||||||||||
Ẹniméjì | |||||||||||
Iye ìdíje | 118–87 (57.56%) | ||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 3 | ||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 17 (2 March 2020) | ||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 17 (16 March 2020) | ||||||||||
Grand Slam Doubles results | |||||||||||
Open Austrálíà | QF (2020) | ||||||||||
Open Fránsì | QF (2019) | ||||||||||
Wimbledon | 3R (2016, 2018) | ||||||||||
Open Amẹ́ríkà | QF (2019) | ||||||||||
Grand Slam Mixed Doubles results | |||||||||||
Open Austrálíà | 2R (2020) | ||||||||||
Open Fránsì | 1R (2017) | ||||||||||
Wimbledon | F (2019) | ||||||||||
Open Amẹ́ríkà | 2R (2017) | ||||||||||
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |||||||||||
Fed Cup | 31–17 (64.58%) | ||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
| |||||||||||
Last updated on: 31 March 2020. |
Jeļena Ostapenko (ọjọ́ìbí 8 June 1997), wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi Aļona Ostapenko,[3] ni agbá tẹ́nìs ará Latvia. Ipò WTA rẹ̀ láàgbáyé tó gajùlọ ni No. 5 nínú àwọn ìdíje ẹnìkan tó dé bẹ̀ ní 19 March 2018, àti No. 17 nínú àwọn ìdíje ẹnimẹ́jì, tó dé bẹ̀ ní 2 March 2020. Ostapenko gba ife-ẹ̀yẹ Open Fránsì odun 2017 nígbà tó bori Simona Halep ní ìparí.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Player Index: Jelena Ostapenko". WTA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ also Glenn Schaap (2018-2019), Jeļena Jakovļeva (her mother), Anabel Medina Garrigues (2017), David Taylor (2018)
- ↑ "Aļona Ostapenko: 'Neviens mani nav tā apmācījis. Tas vienkārši ir stils, kurā spēlēju'" (in lv). Latvijas Avīze. 12 June 2017. http://www.la.lv/alona-ostapenko-neviens-mani-nav-ta-apmacijis-tas-vienkarsi-ir-stils-kura-speleju/. Retrieved 12 June 2017.