Hattie McDaniel
Hattie McDaniel | |
---|---|
Hattie McDaniel ni 1941 | |
Ọjọ́ìbí | Wichita, Kansas, U.S. | Oṣù Kẹfà 10, 1895
Aláìsí | October 26, 1952 Woodland Hills, California, U.S. | (ọmọ ọdún 57)
Iṣẹ́ | Osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 1932–1949 |
Olólùfẹ́ | Larry Williams (1949-1950) (divorced) James Lloyd Crawford (1941-1945) (divorced) Howard Hickman (1938-1938) (divorced) George Langford (1922-1922) (his death) |
Hattie McDaniel (10, osù ke̩fà, o̩dún 1895 – 25, osù ke̩wà, o̩dún 1952) je óṣèrè lobinrin omo Afrika Amerika akoko to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].
Ìgbèsi Àyé Àràbinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]McDaniel jẹ ọmọ to kèrèju ninu awọn ọmọ mẹtala ti awọn óbi rẹ bi. Óṣèrè lóbinrin naa ni à bi ni ọdun 1893 fun awọn ti akó lèru Susan Holbert (Ólórin ti gospel) ati Henry McDaniel ni Winchita, Kansas[2].
McDaniel fẹ Howard Hickman ni óṣu January 19 ni ọdun 1911 ni Denver, Colorado. Howard ku ni ọdun 1915. Ọkọ óṣèrè lóbinrin keji George Langford ku lori egbo ibọn ni óṣu kíní ọdun 1925 ni kó pẹ ti wọn fẹ ara wọn. Hattie fẹ James Lloyd Crawford ni 21 óṣu ke̩ta, ọdun 1941 ti wọn si pinya ni ọdun 1945 lẹyin igbeyawó ọdun mẹrin abọ[3]. Hattie fẹ Larry Williams ni 11 óṣu ke̩fà, ni ọdun 1949 ni Yuma, Arizona ti wọn si pinya ni ọdun 1950[4].
Ni àsiko Ogun Agbaye kèji, Hattie jẹ oludari e̩gbé̩ ti Negro Abala ti Hollywood Victory ti óun ṣẹyẹ fun awọn ologun ti wọn wa ni àwọn ìpìlẹ̀ ológun[5]. Óṣèrè lóbinrin naa darapọ mọ óṣèrè Clarence Muse ti ó jẹ ọkan lara awọn ọmọ ẹgbẹ Alawọ dudu ti óṣèrè Screen Guild lati da ówò fun Red Cross fun awọn ọmọ ilẹ amerika ti ómi yalè àgbàrà ya ṣobu kọlu.
Ikú rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]McDaniel ku lori aisan jẹjẹrẹ ọmu ni ọmọ ọdun 59 ni 26 óṣu ke̩wà ni ọdun 1952 ni ilè iwosan ti lé awòrán ìs̩ípòpadà ni Woodland Hills, California[6][7].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Hattie lọsi ilè iwè ti Denver East lati 1908 de 1910[8].
Ipa Òṣèrè lóbinrin ninu èré àgbèlèwó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Film
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Features
Ọdun | Akọlè | Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwò | Akiyèsi |
---|---|---|---|
1932 | Love Bound | ||
1932 | Impatient Maiden | Injured Patient | uncredited |
1932 | Are You Listening? | Aunt Fatima - Singer | uncredited |
1932 | The Washington Masquerade | Maid | uncredited |
1932 | The Boiling Point | Caroline the Cook | uncredited |
1932 | Crooner | Maid in Ladies' Room | uncredited |
1932 | Blonde Venus | Cora, Helen's Maid in New Orleans | uncredited |
1932 | The Golden West | Mammy Lou | uncredited |
1932 | Hypnotized | Powder Room Attendant | uncredited |
1933 | Hello, Sister | Woman in Apartment House | uncredited |
1933 | I'm No Angel | Tira's Maid-Manicurist | uncredited |
1933 | Goodbye Love | Edna the Maid | uncredited |
1934 | Merry Wives of Reno | Bunny's Maid | uncredited |
1934 | City Park | Tessie - the Ransome Maid | uncredited |
1934 | Operator 13 | Annie | uncredited |
1934 | King Kelly of the U.S.A. | Black Narcissus Mop Buyer | uncredited |
1934 | Judge Priest | Aunt Dilsey | |
1934 | Imitation of Life | Woman at Funeral | uncredited |
1934 | Flirtation | Minor Role | uncredited |
1934 | Lost in the Stratosphere | Ida Johnson | |
1934 | Babbitt | Rosalie, the Maid | uncredited |
1934 | Little Men | Asia | uncredited |
1935 | The Little Colonel | Mom Beck | |
1935 | Transient Lady | Servant | uncredited |
1935 | Traveling Saleslady | Martha Smith | uncredited |
1935 | China Seas | Isabel McCarthy, Dolly's Maid | uncredited |
1935 | Alice Adams | Malena Burns | |
1935 | Harmony Lane | Liza, the Cook | uncredited |
1935 | Murder by Television | Isabella - the Cook | |
1935 | Music Is Magic | Hattie | |
1935 | Another Face | Nellie - Sheila's Maid | uncredited |
1935 | We're Only Human | Molly, Martin's Maid | uncredited |
1936 | Next Time We Love | Hanna | uncredited |
1936 | The First Baby | Dora | |
1936 | The Singing Kid | Maid | uncredited |
1936 | Gentle Julia | Kitty Silvers | |
1936 | Show Boat | Queenie | |
1936 | High Tension | Hattie | |
1936 | The Bride Walks Out | Mamie - Carolyn's Maid | |
1936 | Postal Inspector | Deborah | uncredited |
1936 | Star for a Night | Hattie | |
1936 | Valiant Is the Word for Carrie | Ellen Belle | |
1936 | Libeled Lady | Maid in Grand Plaza Hall | uncredited |
1936 | Can This Be Dixie? | Lizzie | |
1936 | Reunion | Sadie | |
1937 | Racing Lady | Abby | |
1937 | Don't Tell the Wife | Mamie, Nancy's Maid | uncredited |
1937 | The Crime Nobody Saw | Ambrosia | |
1937 | The Wildcatter | Pearl | uncredited |
1937 | Saratoga | Rosetta | |
1937 | Stella Dallas | Maid | |
1937 | Sky Racket | Jenny | |
1937 | Over the Goal | Hannah | |
1937 | Merry Go Round of 1938 | Maid | uncredited |
1937 | Nothing Sacred | Mrs. Walker | uncredited |
1937 | 45 Fathers | Beulah | |
1937 | Quick Money | Hattie | uncredited |
1937 | True Confession | Ella | |
1937 | Mississippi Moods | ||
1938 | Battle of Broadway | Agatha | |
1938 | Vivacious Lady | Hattie - Maid at Prom Dance | uncredited |
1938 | The Shopworn Angel | Martha | |
1938 | Carefree | Hattie | uncredited |
1938 | The Mad Miss Manton | Hilda | |
1938 | The Shining Hour | Belvedere | |
1939 | Everybody's Baby | Hattie | |
1939 | Zenobia | Dehlia | |
1939 | Gone with the Wind | Mammy - House Servant | |
1940 | Maryland | Aunt Carrie | |
1941 | The Great Lie | Violet | |
1941 | Affectionately Yours | Cynthia | |
1941 | They Died with Their Boots On | Callie | |
1942 | The Male Animal | Cleota | |
1942 | In This Our Life | Minerva Clay | |
1942 | George Washington Slept Here | Hester, the Fullers' Maid | |
1943 | Johnny Come Lately | Aida | |
1943 | Thank Your Lucky Stars | Gossip in 'Ice Cold Katie' Number | |
1944 | Since You Went Away | Fidelia | |
1944 | Janie | April - Conway's Maid | |
1944 | Three Is a Family | Maid | |
1944 | Hi, Beautiful | Millie | |
1946 | Janie Gets Married | April | |
1946 | Margie | Cynthia | |
1946 | Never Say Goodbye | Cozie | |
1946 | Song of the South | Aunt Tempy | |
1947 | The Flame | Celia | |
1948 | Mickey | Bertha | |
1948 | Family Honeymoon | Phyllis | |
1949 | The Big Wheel | Minnie |
Short films
Ọdun | Àkọlè | Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwó | Àkiyèsi |
---|---|---|---|
1934 | Mickey's Rescue | Maid | uncredited |
1934 | Fate's Fathead | Mandy - the Maid | uncredited |
1934 | The Chases of Pimple Street | Hattie, Gertrude's Maid | uncredited |
1935 | Anniversary Trouble | Mandy, the Maid | Our Gang |
1935 | Okay Toots! | Hattie - the Maid | uncredited |
1935 | Wig-Wag | Cook | uncredited |
1935 | The Four Star Boarder | Maid | uncredited |
1936 | Arbor Day | Buckwheat's Mother | Our Gang |
1938 | Termites of 1938 | Three Stooges |
Radio
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdun | Program | Episode/source |
---|---|---|
1941 | Gulf Screen Guild Theatre | No Time for Comedy |
Àmi Ẹyẹ ati Idànilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Hattie jẹ óṣèrè lóbinrin ilẹ Afirika ati Amerika to mà gbà amin ẹyẹ Oscar[9]. Óṣèrè lóbinrin naa gbà irawọ meji lori Hollywood walk of fame ti wọn si gba wọlè si Awọn Alawọ dudu ti wọn jẹ óṣere Hall of Fame ni ọdun 1975. Hattie jẹ akọkọ Ẹni tó gba Oscar ti wọn fun Postage Stage ti ilẹ U.S gẹgẹbi àmi idàlọla to waye ni ọdun 2006[10]. Ni ọdun 2010 ni wọn gba óṣèrè lóbinrin wọlè si Colorado Hall ti Fame ti awọn obinrin[11].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.biography.com/actor/hattie-mcdaniel
- ↑ https://web.archive.org/web/20130524233831/http://www.blackclassicmovies.com/articles/people/hattie-mcdaniel.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20070930093005/http://www.time.com/time/magazine/article/0,9171,886791,00.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20070930075946/http://www.time.com/time/magazine/article/0,9171,859034,00.html
- ↑ https://web.archive.org/web/20101209000623/http://cghs.dade.k12.fl.us/african-american/reconstruct/hattie_mcdaniel.htm
- ↑ http://www.cemeteryguide.com/mcdaniel.html
- ↑ https://hollywoodforever.com/story/hattie-mcdaniel/
- ↑ https://www.coloradovirtuallibrary.org/digital-colorado/colorado-histories/20th-century/hattie-mcdaniel-actress/
- ↑ https://www.hollywoodreporter.com/movies/movie-news/oscars-first-black-winner-accepted-774335/
- ↑ https://web.archive.org/web/20080707100527/http://www.usps.com/communications/news/stamps/2006/sr06_005.htm
- ↑ https://www.cogreatwomen.org/project/hattie-mcdaniel/