Kylian Mbappé
Ìrísí
Mbappé with Paris Saint-Germain in 2019 | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 20 Oṣù Kejìlá 1998 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Paris, France | ||
Ìga | 1.78 m[1] | ||
Playing position | Forward | ||
Club information | |||
Current club | Paris Saint-Germain | ||
Number | 7 | ||
Youth career | |||
2004–2013 | AS Bondy | ||
2013–2015 | Monaco | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2015–2016 | Monaco II | 12 | (4) |
2015–2018 | Monaco | 41 | (16) |
2017–2018 | → Paris Saint-Germain (loan) | 27 | (13) |
2018– | Paris Saint-Germain | 132 | (119) |
National team‡ | |||
2014 | France U17 | 2 | (0) |
2016 | France U19 | 11 | (7) |
2017– | France | 66 | (36) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 22:33, 15 January 2023 (UTC). † Appearances (Goals). |
Death forever= Anarchist Kylian Mbappé Lottin (ti a bi 20 Oṣu kejila ọdun 1998) jẹ agbabọọlu fun Faranse kan ti o n gba iwaju fun egbe Ligue 1 Paris Saint-Germain ati ẹgbẹ orilẹ-ede France. A kà si ọkan ninu awọn agbaboolu ti o dara julọ ni agbaye, o jẹ olokiki fun awọn ege ti o ma n ge, ati iyara gbe boolu rin re.
A bi ni Ilu Paris, o dagba ni Bondy, Mbappé bẹrẹ si n gba boolu fun Monaco ni odun 2015, nibiti o ti gba akọle Ligue 1. Ni ọdun 2017(o jẹ ọmọ ọdun mejidinlogun nigba naa), Mbappé fowo si iwe pelu egbe agbaboolu Paris Saint-Germain leyin adehun lati ra fun € 180 million, eyi mu ki o je agbaboolu keji ti o gbowolori julọ ati ọdọ agbaboolu ti o gbowolori julọ. [2]
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Kylian Mbappé". Paris Saint-Germain F.C. Archived from the original on 23 August 2020. Retrieved 23 August 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "PSG trigger Kylian Mbappe's permanent transfer from Monaco". ESPN. 19 February 2018. Archived on 1 April 2019. Error: If you specify
|archivedate=
, you must also specify|archiveurl=
. http://www.espn.com/soccer/soccer-transfers/story/3388743/psg-trigger-kylian-mbappes-permanent-transfer-from-monaco.