Asif Ali Zardari
Ìrísí
Asif Ali Zardari آصف علی زرداری آصف علي زرداري | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Pakístàn | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 March 2024 | |
Alákóso Àgbà | Shehbaz Sharif |
Asíwájú | Arif Alvi |
In office 9 September 2008 – 9 September 2013 | |
Alákóso Àgbà | Yousaf Raza Gillani Raja Pervaiz Ashraf Mir Hazar Khan Khoso (Caretaker) Nawaz Sharif |
Asíwájú | Muhammad Mian Soomro (Acting) |
Arọ́pò | Mamnoon Hussain |
Abáṣe-Alága Ẹgbẹ́ Àwọn Èníyàn Pakístàn | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 30 December 2007 Serving with Bilawal Zardari Bhutto | |
Asíwájú | Benazir Bhutto |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Keje 1955 Karachi, Pakistan[1] |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Benazir Bhutto (1987–2007) |
Àwọn ọmọ | Bilawal Bakhtawar Asifa |
Residence | Islamabad, Pakistan |
Asif Ali Zardari (Urdu: آصف علی زرداری; Sindhi: آصف علي زرداري; ojoibi 26 July 1955) ni Aare ile Pakistan 11k lowolowo ati Abase-Alaga Egbe Awon Eniyan Pakistan (PPP). Zardari ni opó-kùnrin Benazir Bhutto, eni to je Alakoso Agba ile Pakistan ni emeji. Nigba ti iyawo re je didakupa ni Osu Kejila 2007, o di olori egbe PPP. Awon kan ti wi pe Zardari ni ikan larin awon olowojulo marun ni Pakistan pelu idiye iyi ohun ini to to US$1.8 billion (2005).[5][6]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ [https://web.archive.org/web/20120620142443/http://www.presidentofpakistan.gov.pk/index.php Archived 2012-06-20 at the Wayback Machine.? lang=en&opc=2&sel=2
- ↑ "The Martyrdom of Benazir Bhutto". Huffingtonpost.com. 2008-01-03. Retrieved 2010-08-06.
- ↑ Vali Nasr The Shia Revival: How Conflicts Within Islam Will Shape the Future (W. W. Norton, 2006), pp. 88-90 ISBN 0-393-32968-2
- ↑ Bokhari, Farhan (2010-11-29). "Pakistan-Saudi Relations Appear Strained in Leaked Cables". CBS News. Archived from the original on 2012-07-28. https://archive.is/SLO3.
- ↑ Malik, Salik (2008-10-26). "President Asif Ali Zardari 2nd most Richest man of Pakistan | Pakistan Daily". Daily.pk. Archived from the original on 2012-01-13. Retrieved 2010-08-06.
- ↑ Burns, John F. (1998-01-09). "HOUSE OF GRAFT - Tracing the Bhutto Millions - A special report. - Bhutto Clan Leaves Trail of Corruption - Special Report". Pakistan: NYTimes.com. http://www.nytimes.com/1998/01/09/world/house-graft-tracing-bhutto-millions-special-report-bhutto-clan-leaves-trail.html. Retrieved 2010-08-06.