Ìdarapọ̀mọ́ra kẹ́míkà
Idarapomora kemika je igbese to n fa iyipada akojopo ohun kemika si omiran.[1] Awon idarapomora kemika je ohun ti awon onimo kemistri nko ninu papa sayensi to n je kemistri. Awon idarapomora kemika le je lojiji, ti ko fe okun/agbara kankan, tabi alaije lojiji, to le sele leyin igbati a ba se afikun iru okun/agbara kan sibe, fun apere igbona, imole tabi itanna. Awon idarapomora kemika je awon iyipada to je mo irin awon elektroni lati da tabi tuka awon isorapo kemika, botilejepe itumo gbogbogbo idarapomora kemika, agaga bo se je ti isodogba kemika, wulo fun iyipada awon elementary particles, ati fun awon idarapomora tinuatomu.
Ohun/awon ohun to bere idarapomora kemika ni a npe ni awon oludarapomora. Idarapomora kemika nfa iyipada kemika wa, eyi le mu eso kan tabi pupo wa, ti ohun ini won yato si ti awon oludarapomora.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |