Ngozi Okobi
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ngozi Sonia Okobi-Okeoghene | ||
Ọjọ́ ìbí | 14 Oṣù Kejìlá 1993 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.65m | ||
Playing position | Forward | ||
Club information | |||
Current club | Eskilstuna United DFF | ||
Number | 25 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2010–2015 | Delta Queens | ||
2015 | Washington Spirit | 4 | (0) |
2016–2017 | Vittsjö GIK | 38 | (3) |
2018– | Eskilstuna United DFF | 68 | (6) |
National team‡ | |||
2010– | Nigeria women's national football team | 27 | (4) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 30 August 2020. † Appearances (Goals). |
Ngozi Okobi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 14, óṣu December ni ọdun 1993. Arabinrin naa ṣere fun Swedish club Eskilstuna United DFF gẹgẹbi ipo forward[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ngozi kopa ninu FIFA U-17 Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2008, 2010 ati FIFA U-20 Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2012 nibi ti o jẹ àṣoju team awọn obinrin apapọ ilẹ naigiria lori bọọlu[4].
- Ngozi kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2010, 2012 ati 2014[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://us.soccerway.com/players/ngozi-okobi/150697/
- ↑ https://www.eurosport.com/football/ngozi-okobi_prs326806/person.shtml
- ↑ https://globalsportsarchive.com/people/soccer/ngozi-okobi/157050/
- ↑ https://www.fifa.com/tournaments/womens/u17womensworldcup/trinidadandtobago2010/teams/1915218
- ↑ https://www.playmakerstats.com/player.php?id=287671&edicao_id=105111