Miguel (akọrin)
Miguel Jontel Pimentel (ti a bi ni Oṣùu Kẹwa Ọjọ́ 23, Ọdún 1985) jẹ́ akọrin, akọ̀wé-orin, olóòtú àwo-orin, àti òṣeré ará Amẹ́ríkà. Wọ́n tọ́ ọ dàgbà ní San Pedro, California, o bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin nígbà tó tó ọmọ-ọdún mẹ́tàlá. Lẹ́hìn tó darapọ̀ mọ́ Jive Records ni ọdún 2007, Miguel ṣe àgbéjáde àwo-orin, ''All I Want Is You" ni Oṣù kọkànlá ọdún 2010. Bíótilẹ̀jẹ́pé wọn kò polówó rẹ̀ nígbàtí wọ́n ṣe àgbéjáde rẹ̀, àwo-orin náà di oorun ti o kọlu o ṣe iranlọwọ fun Miguel garner ti iṣowo iduro. [9]
Miguel | |
---|---|
Miguel at the 2019 iHeartRadio Music Awards | |
Ọjọ́ìbí | Miguel Jontel Pimentel 23 Oṣù Kẹ̀wá 1985[1] Los Angeles, California U.S.[2] |
Orúkọ míràn | Jontel Johnson[3] |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2000–present |
Agent | Mark Pitts Wayne Barrow |
Olólùfẹ́ | Nazanin Mandi (m. 2018) |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels | |
Associated acts |
|
Website | officialmiguel.com |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Miguel - Singer - Biography". Biography. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Jeddah, Birth Index, 1905-1985
- ↑ [1]
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedNero
- ↑ Jeffries, David. "Miguel - Music Biography, Credits and Discography". AllMusic. Retrieved 2012-10-24.
- ↑ "New wave of neo-soul". Chicago Tribune. October 11, 2013. Archived from the original on August 22, 2018. Retrieved August 21, 2018.
- ↑ Carley, Brennan (August 22, 2012). "Frank Ocean, Miguel, and Holy Other Usher in PBR&B 2.0". Spin. Retrieved 2015-06-26.
- ↑ "Check Out: six tracks from Miguel's "Kaleidoscope Dream"". Pretty Much Amazing. Retrieved 2015-06-26.
- ↑ Rytlewski, Evan (October 9, 2012). "Miguel: Kaleidoscope Dream". Archived from the original on 2012-12-30. https://web.archive.org/web/20121230044645/http://www.avclub.com/articles/miguel-kaleidoscope-dream%2C86389/. Retrieved 2012-10-19.